YORUBA PREACHER’S BIBLE

10,000.00

Categories: ,

Description

BÍBÉLÌ MÍMỌ́ [PLU ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÀWN ONÍWÀÁSÙ]

Bíbélì Mímọ́ tí a ṣe pẹlu àfojúsùn láti mú kí ó rọrùn fún àwọn Oníwàásù láti gbáradì fún ìwàásù, ati fún àwọn tó fẹ́ ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìmọ̀ nínú Bíbélì.

Àwọn èròjà mìíràn tó wà nínú Bíbélì yìí ni:

  • Ẹgbẹ̀sán [1,800] ìlàkalẹ̀ fún ìwàásù
  • Ìrànlọ́wọ́ ìpalẹ̀mọ́ fún ìwàásù
  • Ìfáàrà sí ìwé Bíbélì kọ̀ọ̀kan
  • Ìlàkalẹ̀ àwọn àkòrí inú ìwé kọ̀ọ̀kan
  • Ìtọ́kasí ẹsẹ Bíbélì ní àfibọ̀ ẹsẹ kọ̀ọ̀kan
  • Ó rọrùn láti gbé ká

Dimension: 233 x 168mm

Additional information

Weight 1.5 kg

Reviews

There are no reviews yet

Only logged in customers who have purchased this product may leave a review.